Orin Dafidi 96:12 BM

12 Jẹ́ kí pápá oko ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ yọ̀.Nígbà náà ni gbogbo igi igbó yóo fi ayọ̀ kọrin,

Ka pipe ipin Orin Dafidi 96

Wo Orin Dafidi 96:12 ni o tọ