Orin Dafidi 99:7 BM

7 Ó bá wọn sọ̀rọ̀ ninu ọ̀wọ̀n ìkùukùu;wọ́n pa òfin rẹ̀ mọ́;wọ́n sì tẹ̀lé ìlànà tí ó fún wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 99

Wo Orin Dafidi 99:7 ni o tọ