1 Ẹ yin OLUWA!Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeunnítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 106
Wo Orin Dafidi 106:1 ni o tọ