3 Aya rẹ yóo dàbí àjàrà eléso pupọ ninu ilé rẹ;bí ọmọ tií yí igi olifi ká,ni àwọn ọmọ rẹ yóo yí tabili oúnjẹ rẹ ká.
4 Wò ó, bẹ́ẹ̀ ni OLUWA yóo kẹ́ ẹni tí ó bẹ̀rù rẹ̀.
5 Kí OLUWA bukun ọ láti Sioni!Kí o máa rí ire Jerusalẹmuní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.
6 Kí o máa rí arọmọdọmọ rẹ.Kí alaafia máa wà ní Israẹli.