Orin Dafidi 139:4 BM

4 Kódà kí n tó sọ ọ̀rọ̀ jáde lẹ́nu,OLUWA, o ti mọ gbogbo nǹkan tí mo fẹ́ sọ patapata.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 139

Wo Orin Dafidi 139:4 ni o tọ