7 Ìbá ti dára tó kí ìgbàlà Israẹli ti Sioni wá!Nígbà tí OLUWA bá dá ire àwọn eniyan rẹ̀ pada,Jakọbu yóo yọ̀, inú Israẹli yóo sì dùn.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 14
Wo Orin Dafidi 14:7 ni o tọ