Orin Dafidi 141:6 BM

6 Nígbà tí ọwọ́ àwọn tí yóo dá wọn lẹ́bi bá tẹ̀ wọ́n,wọn óo gbà pé, òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ OLUWA.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 141

Wo Orin Dafidi 141:6 ni o tọ