Orin Dafidi 141:5 BM

5 N ò kọ̀ kí ẹni rere bá mi wí,n ò kọ̀ kí ó nà mí;kí ó ṣá ti fi ìfẹ́ bá mi wí.Ṣugbọn má jẹ́ kí eniyan burúkú tilẹ̀ ta òróró sí mi lórí,nítorí pé nígbàkúùgbà ni mò ń fi adura tako ìwà ibi wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 141

Wo Orin Dafidi 141:5 ni o tọ