12 Ẹ júbà ọmọ náà, kí ó má baà bínú,kí ó má baà pa yín run lójijì;nítorí a máa yára bínú.Ayọ̀ ń bẹ fún gbogbo àwọn tí ó wá ààbò lọ sọ́dọ̀ rẹ̀.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 2
Wo Orin Dafidi 2:12 ni o tọ