9 Ìwọ óo fi ọ̀pá irin fọ́ wọn,o óo sì fọ́ wọn túútúú bí ìkòkò amọ̀.”
10 Nítorí náà, ẹ̀yin ọba, ẹ kọ́gbọ́n;ẹ̀yin onídàájọ́ ayé, ẹ gba ìkìlọ̀.
11 Ẹ fi ìbẹ̀rù sin OLUWA,ẹ yọ̀ pẹlu ìwárìrì.
12 Ẹ júbà ọmọ náà, kí ó má baà bínú,kí ó má baà pa yín run lójijì;nítorí a máa yára bínú.Ayọ̀ ń bẹ fún gbogbo àwọn tí ó wá ààbò lọ sọ́dọ̀ rẹ̀.