Orin Dafidi 22:24 BM

24 Nítorí pé kò fi ojú pa ìjìyà àwọn tí à ń jẹ níyà rẹ́;kò sì ṣá wọn tì,bẹ́ẹ̀ ni kò fi ojú pamọ́ fún wọn,ṣugbọn ó gbọ́ nígbà tí wọ́n ké pè é.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 22

Wo Orin Dafidi 22:24 ni o tọ