Orin Dafidi 22:29 BM

29 Gbogbo àwọn agbéraga láyé ni yóo wólẹ̀ níwájú rẹ̀;gbogbo ẹni tí yóo fi ilẹ̀ bora bí aṣọni yóo wólẹ̀ níwájú rẹ̀,àní, gbogbo àwọn tí kò lè dá sọ ara wọn di alààyè.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 22

Wo Orin Dafidi 22:29 ni o tọ