7 Dìde, OLUWA, gbà mí, Ọlọrun mi!Nítorí ìwọ ni o lu gbogbo àwọn ọ̀tá mi bolẹ̀,tí o sì ṣẹgun àwọn eniyan burúkú.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 3
Wo Orin Dafidi 3:7 ni o tọ