5 Ìwọ ọkàn mi, kí ló dé tí o fi rẹ̀wẹ̀sì?Kí ló dé tí ara rẹ kò fi balẹ̀ ninu mi?Gbẹ́kẹ̀ rẹ lé Ọlọrun, nítorí pé n óo tún yìn ín,olùrànlọ́wọ́ mi ati Ọlọrun mi.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 42
Wo Orin Dafidi 42:5 ni o tọ