Orin Dafidi 52:5 BM

5 Nítòótọ́ Ọlọrun óo bá ọ kanlẹ̀,yóo gbá ọ mú, yóo sì fà ọ́ já kúrò ninu ilé rẹ;yóo fà ọ́ tu kúrò lórí ilẹ̀ alààyè.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 52

Wo Orin Dafidi 52:5 ni o tọ