Orin Dafidi 52:6 BM

6 Nígbà tí àwọn olódodo bá rí i, ẹ̀rù óo bà wọ́n,wọn óo fi rẹ́rìn-ín, wọn óo sì wí pé,

Ka pipe ipin Orin Dafidi 52

Wo Orin Dafidi 52:6 ni o tọ