Orin Dafidi 53:5 BM

5 Ẹ wò wọ́n, bí wọ́n ṣe wà ninu ẹ̀rù ńlá,ẹ̀rù tí kò tíì sí irú rẹ̀ rí!Nítorí Ọlọrun yóo fọ́n egungun àwọn ọ̀tá rẹ̀ ká;ojú óo tì wọ́n, nítorí Ọlọrun ti kọ̀ wọ́n.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 53

Wo Orin Dafidi 53:5 ni o tọ