6 Ìbá ti dára tó, kí ìgbàlà Israẹli ti Sioni wá!Nígbà tí Ọlọrun bá dá ire àwọn eniyan rẹ̀ pada,Jakọbu yóo yọ̀, inú Israẹli yóo sì dùn.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 53
Wo Orin Dafidi 53:6 ni o tọ