Orin Dafidi 56:13 BM

13 Nítorí pé o ti gba ẹ̀mí mi lọ́wọ́ ikú,o gbà mí, o kò jẹ́ kí n kọsẹ̀,kí n lè máa rìn níwájú Ọlọrunninu ìmọ́lẹ̀ ìyè.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 56

Wo Orin Dafidi 56:13 ni o tọ