Orin Dafidi 78:5 BM

5 Ó fi ìlànà lélẹ̀ fún ìdílé Jakọbu;ó gbé òfin kalẹ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli.Ó pa á láṣẹ fún àwọn baba ńlá wa,pé kí wọ́n fi kọ́ àwọn ọmọ wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 78

Wo Orin Dafidi 78:5 ni o tọ