Orin Dafidi 78:6 BM

6 Kí àwọn ìran tí ń bọ̀ lè mọ̀ ọ́n,àní, àwọn ọmọ tí a kò tíì bí,kí àwọn náà ní ìgbà tiwọnlè sọ ọ́ fún àwọn ọmọ wọn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 78

Wo Orin Dafidi 78:6 ni o tọ