Orin Dafidi 88:5 BM

5 N kò yàtọ̀ sí ẹni tí a pa tì sí apá kan láàrin àwọn òkú,mo dàbí ẹni tí a pa, tí ó sùn ninu ibojì,bí àwọn tí ìwọ kò ranti mọ́,nítorí pé wọ́n ti kúrò lábẹ́ ìtọ́jú rẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 88

Wo Orin Dafidi 88:5 ni o tọ