14 Wọn á máa so èso títí di ọjọ́ ogbó wọn,wọn á máa lómi lára, ewé wọn á sì máa tutù nígbà gbogbo;
Ka pipe ipin Orin Dafidi 92
Wo Orin Dafidi 92:14 ni o tọ