6 Nígbà tí ọwọ́ àwọn tí yóo dá wọn lẹ́bi bá tẹ̀ wọ́n,wọn óo gbà pé, òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ OLUWA.
7 Bí òkúta tí eniyan là, tí ó fọ́ yángá-yángá sílẹ̀,ni a óo fọ́n egungun wọn ká sí ẹnu ibojì.
8 Ṣugbọn ìwọ ni mo gbójúlé, OLUWA, Ọlọrun.Ìwọ ni asà mi,má fi mí sílẹ̀ láìní ààbò.
9 Pa mí mọ́ ninu ewu tàkúté,ati ti okùn tí àwọn aṣebi dẹ sílẹ̀ dè mí.
10 Jẹ́ kí àwọn eniyan burúkú ṣubú sinu àwọ̀n ara wọn,kí èmi sì lọ láìfarapa.