Sáàmù 103:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n láti ayé rayé ni ìfẹ́ Olúwa ti wà pẹ̀lú àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ̀,àti òdodo Rẹ̀ wà láti ọmọ dé ọmọ

Ka pipe ipin Sáàmù 103

Wo Sáàmù 103:17 ni o tọ