45 Ó rántí májẹ̀mú Rẹ̀ nítorí wọnNítorí agbára ìfẹ́ Rẹ̀, ó ṣàánú wọn.
46 Lójú gbogbo àwọn tí o kó wọn ní ìgbèkùnó mú wọn rí àánú.
47 Gbà wá, Olúwa Ọlọ́run wa,kí o sì ṣà wá jọ kúrò láàrin àwọn aláìkọlàláti máa fí ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ Rẹláti máa ṣògo nínú ìyìn Rẹ.
48 Olùbùkún ni Olúwa,Ọlọ́run Ísírẹ́lì, láti ìrandíranJẹ́ kí gbogbo ènìyàn kí ó wí pé, “Àmín!”Ẹ fi ìyìn fún Olúwa!