3 Ọlá àti ọrọ̀ yóò wà nínú ilé Rẹ̀:òdodo Rẹ̀ sì dúró láé.
4 Fún olóòótọ́ ni ìmọ́lẹ̀ yóò tàn fún ni òkùnkùn:olóore ọ̀fẹ́ àti aláàánú àti òdodo.
5 Ọkùnrin rere fí ojú rere hàn, a sì wín ni,ìmòye ni yóò máa fi la ọ̀nà iṣẹ́ Rẹ̀.
6 Dájúdájú kì yóò le yí ni ìpo padà láéláé:olódodo ni a ó máa ṣe ìrántí ní ayérayé.
7 Òun kì yóò bèèrè ìyìn búburú:ọkàn Rẹ̀ ti dúró, ó ní ìgbẹ́kẹ̀lé nínú Olúwa.
8 Ó ti mú ọkàn Rẹ̀ gbilẹ̀, ẹ̀rù kí yóò bàá,títí yóò fi rí ìfẹ́ ọkan Rẹ̀ lórí àwọn ọ̀tá Rẹ̀.
9 Ó ti pin ká, ó ti fi fún àwọn olùpọ́njú;Nítorí òdodo Rẹ̀ dúró láé;ìwọ Rẹ̀ ní a ó gbé sókè pẹ̀lú ọlá.