4 Olúwa ga lórí gbogbo ayé,àti ògo Rẹ̀ lórí àwọn ọ̀run.
5 Ta ló dàbí Olúwa Ọlọ́run wa,tí ó gbé ní ibi gíga.
6 Tí ó Rẹ ara Rẹ̀ sílẹ̀ láti wòòun tí ó ń bẹ lọ́run, àti nínú ayé!
7 Ó gbé òtòsì dìde láti inú erùpẹ̀, àti péó gbé aláìní sókè láti inú ààtàn wá.
8 Kí ó le mú-un jókòó pẹ̀lú àwọn ọmọ aládéàní pẹ̀lú àwọn ọmọ aládé àwọn ènìyàn Rẹ̀.
9 Ó mú àgàn obìnrin gbé inú ilé,àti láti jẹ́ aláyọ̀ ìyá fún àwọn ọmọ Rẹ̀.Ẹ yin Olúwa.