Sáàmù 117:1 BMY

1 Ẹ yin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀ èdè;ẹ pòkìkí Rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.

Ka pipe ipin Sáàmù 117

Wo Sáàmù 117:1 ni o tọ