Sáàmù 119:28 BMY

28 Ọkàn mi ń ṣe àárẹ̀ pẹ̀lú ìbànújẹ́;fi agbára fún mi gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 119

Wo Sáàmù 119:28 ni o tọ