Sáàmù 123:2 BMY

2 Kíyèsí, bí ojú àwọnìránṣẹ́ kùnrin ti máa ń wo ọwọ́ àwọn baba wọn,àti bí ojú ìránṣẹ́-bìnrin ti máa ń wo ọwọ́ ìyá Rẹ̀bẹ́ẹ̀ ni ojú wa ń wo Olúwa Ọlọ́run wa,títí yóò fi ṣàánú fún wa.

Ka pipe ipin Sáàmù 123

Wo Sáàmù 123:2 ni o tọ