Sáàmù 13:1 BMY

1 Yóò ti pẹ́ tó, Olúwa? Ìwọ o ha gbàgbé mi títí láé?yóò tí pẹ́ tó tí ìwọ yóò máa fi ojú Rẹ pamọ́ fún mi?

Ka pipe ipin Sáàmù 13

Wo Sáàmù 13:1 ni o tọ