6 Bí èmi kò bá rántí Rẹ,jẹ́ kí ahọ́n mi kí ó lẹ̀ mọ́ èrìgì mi;bí èmi kò bá fi Jérúsálẹ́mù ṣáájúolórí ayọ̀ mi gbogbo.
7 Olúwa rántí ọjọ́ Jérúsálẹ́mù,lára àwọn ọmọ Édómù,àwọn ẹni tí ń wí pé,wó o palẹ̀, wó o palẹ̀ de ìpílẹ̀ Rẹ̀!
8 Ìwọ, ọmọbìnrin Bábílónì, ẹni tí a o parun;ìbùkún ní fún ẹni tí ó san án fúnọ bí ìwọ ti rò sí wa.
9 Ìbùkún ní fún ẹni tí ó mú tí ó sì fiọmọ wẹ́wẹ́ Rẹ̀ ṣán òkúta.