Sáàmù 139:16 BMY

16 Ojú Rẹ̀ ti rí ohun ara mi tí ó wà láìpé:àti nínú ìwé Rẹ ni a ti kọ gbogbo wọn sí,ní ojojumọ́ ni a ń dá wọn,nígbà tí ọ̀kan wọn kò tí i sí.

Ka pipe ipin Sáàmù 139

Wo Sáàmù 139:16 ni o tọ