21 Olúwa, ǹjẹ́ èmi kò korìíra àwọn tó korìíra Rẹ?Ǹjẹ́ inú mi kò a sì bàjẹ́ sí àwọn tí ó dìde sí ọ?
Ka pipe ipin Sáàmù 139
Wo Sáàmù 139:21 ni o tọ