2 Olúwa ni àpáta àti odi mi, àti olùgbàlà mi;Ọlọ́run mi ni àpáta mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ìsádi mi.Òun ni àpáta ààbò àti agbára ìgbàlà mi àti ibi ìsádi mi.
Ka pipe ipin Sáàmù 18
Wo Sáàmù 18:2 ni o tọ