Sáàmù 18:28 BMY

28 Ìwọ, Olúwa, jẹ́ kí fìtílà mikí ó máa tàn; Ọlọ́run mi, yí òkùnkùn mi padà sí ìmọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 18

Wo Sáàmù 18:28 ni o tọ