Sáàmù 18:30 BMY

30 Bí ó ṣe ti Ọlọ́run mi, ọ̀nà Rẹ̀ pé,a ti rídìí ọ̀rọ̀ Olúwaòun ni àpáta ààbòfún gbogbo àwọn tí ó fi ṣe ààbò.

Ka pipe ipin Sáàmù 18

Wo Sáàmù 18:30 ni o tọ