Sáàmù 18:50 BMY

50 Ó fún Ọba Rẹ̀ ni ìṣẹ́gun ńlá;ó fi ìkáànú àìṣẹ̀tàn fún ẹni-àmì-òróró Rẹ̀,fún Dáfídì àti ìran Rẹ̀ títí láé.

Ka pipe ipin Sáàmù 18

Wo Sáàmù 18:50 ni o tọ