Sáàmù 20:1 BMY

1 Kí Olúwa kí ó gbóhùn Rẹ̀ ní ọjọ́ ìpọ́njú;kí orúkọ Ọlọ́run Jákọ́bù kí ó dáàbòbò ọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 20

Wo Sáàmù 20:1 ni o tọ