Sáàmù 20:7 BMY

7 Àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé kẹ̀kẹ́, àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé ẹṣin,ṣùgbọ́n àwa gbẹ́kẹ̀ lé orúkọ Olúwa Ọlọ́run wa.

Ka pipe ipin Sáàmù 20

Wo Sáàmù 20:7 ni o tọ