Sáàmù 26:3 BMY

3 Nítorí ìfẹ́ ẹ̀ Rẹ tí ó dúró ṣinṣin ń bẹ níwájú mi,èmí sì ti rìn nínú òtítọ́ Rẹ.

Ka pipe ipin Sáàmù 26

Wo Sáàmù 26:3 ni o tọ