Sáàmù 27:1 BMY

1 Olúwa ni ìmọ́lẹ̀ mi àti ìgbàlà mi;ta ni èmi yóò bẹ̀rù? Olúwa ni ibi olódì ẹ̀mí mi,ta ni ẹni tí èmi yóò bẹ̀rù?

Ka pipe ipin Sáàmù 27

Wo Sáàmù 27:1 ni o tọ