Sáàmù 28:3 BMY

3 Má ṣe fà mí lọ pẹ̀lú ènìyàn búburú àti,pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀,tí ń sọ̀rọ̀ àlàáfíà sí aládùúgbò wọnṣùgbọ́n tí ìwà ìkà ń bẹ nínú wọn.

Ka pipe ipin Sáàmù 28

Wo Sáàmù 28:3 ni o tọ