Sáàmù 28:7 BMY

7 Olúwa ni agbára mi àti aṣà mi;nínú Rẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀lé; àní, ó sì ràn mí lọ́wọ́.ọkàn mi sì gbé sókè fún ayọ̀àni pẹ̀lú orin mi mo fi ọpẹ́ fún un.

Ka pipe ipin Sáàmù 28

Wo Sáàmù 28:7 ni o tọ