10 Olúwa jókòó, Ó sì jọba lórí ìṣàn omi; Olúwa jókòó lórí ìtẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọbatítí láéláé.
Ka pipe ipin Sáàmù 29
Wo Sáàmù 29:10 ni o tọ