Sáàmù 31:12 BMY

12 Èmi ti di ẹni ìgbàgbé kúrò ní ọkàn gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó ti kú;Èmi sì dàbí ohun èlò tí ó ti fọ́.

Ka pipe ipin Sáàmù 31

Wo Sáàmù 31:12 ni o tọ