Sáàmù 34:2 BMY

2 Ọkàn mí yóò máa ṣògo nínú Olúwa;jẹ́ kí àwọn onírẹ̀lẹ̀ gbọ́ kí inú wọn kí ó sì máa dùn.

Ka pipe ipin Sáàmù 34

Wo Sáàmù 34:2 ni o tọ