8 Àsè ilé Rẹ yóò tẹ́ wọn lọ́rùngidigidi; ìwọ yóò sì mú wọn munínú odò inú-dídùn Rẹ.
Ka pipe ipin Sáàmù 36
Wo Sáàmù 36:8 ni o tọ