Sáàmù 38:1 BMY

1 OlúwaMá ṣe bá mi wí nínú ìbínú Rẹ,bẹ́ẹ̀ ni kí o má ṣe fi ìyà jẹ mínínú ìrunú Rẹ̀.

Ka pipe ipin Sáàmù 38

Wo Sáàmù 38:1 ni o tọ